Dáníẹ́lì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́, màá sọ àwọn nǹkan tí a kọ sínú ìwé òtítọ́ fún ọ. Kò sí ẹni tó ń tì mí lẹ́yìn gbágbáágbá nínú àwọn nǹkan yìí, àfi Máíkẹ́lì,+ olórí yín.+
21 Àmọ́, màá sọ àwọn nǹkan tí a kọ sínú ìwé òtítọ́ fún ọ. Kò sí ẹni tó ń tì mí lẹ́yìn gbágbáágbá nínú àwọn nǹkan yìí, àfi Máíkẹ́lì,+ olórí yín.+