Dáníẹ́lì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, ó sún mọ́ ibi tí mo dúró sí, àmọ́ nígbà tó dé, ẹ̀rù bà mí débi pé mo dojú bolẹ̀. Ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, jẹ́ kó yé ọ pé àkókò òpin ni ìran náà wà fún.”+ Dáníẹ́lì 8:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Òótọ́ ni ohun tí wọ́n sọ nínú ìran náà nípa alẹ́ àti àárọ̀, àmọ́ kí o ṣe ìran náà ní àṣírí, torí ọ̀pọ̀ ọjọ́ sí àkókò yìí* ló ń tọ́ka sí.”+ Dáníẹ́lì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sì sọ pé: “Máa lọ, Dáníẹ́lì, torí pé ọ̀rọ̀ náà máa jẹ́ àṣírí, a sì máa gbé èdìdì lé e títí di àkókò òpin.+
17 Torí náà, ó sún mọ́ ibi tí mo dúró sí, àmọ́ nígbà tó dé, ẹ̀rù bà mí débi pé mo dojú bolẹ̀. Ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, jẹ́ kó yé ọ pé àkókò òpin ni ìran náà wà fún.”+
26 “Òótọ́ ni ohun tí wọ́n sọ nínú ìran náà nípa alẹ́ àti àárọ̀, àmọ́ kí o ṣe ìran náà ní àṣírí, torí ọ̀pọ̀ ọjọ́ sí àkókò yìí* ló ń tọ́ka sí.”+
9 Ó sì sọ pé: “Máa lọ, Dáníẹ́lì, torí pé ọ̀rọ̀ náà máa jẹ́ àṣírí, a sì máa gbé èdìdì lé e títí di àkókò òpin.+