ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 7:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Lẹ́yìn èyí, mò ń wò nínú ìran òru, mo sì rí ẹranko kẹrin, ó ń bani lẹ́rù, ó sì ń dáyà jáni, agbára rẹ̀ ṣàrà ọ̀tọ̀, ó sì ní eyín ńlá tó jẹ́ irin. Ó ń jẹ nǹkan run, ó ń fọ́ nǹkan túútúú, ó sì ń fi ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ohun tó ṣẹ́ kù mọ́lẹ̀.+ Ó yàtọ̀ sí gbogbo ẹranko yòókù tó wà ṣáájú rẹ̀, ó sì ní ìwo mẹ́wàá.

  • Dáníẹ́lì 7:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Mo fẹ́ mọ̀ sí i nípa ẹranko kẹrin, tó yàtọ̀ sí gbogbo àwọn yòókù; ó ń bani lẹ́rù lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀, ó ní eyín irin àti èékánná bàbà, ó ń jẹ nǹkan run, ó ń fọ́ nǹkan túútúú, ó sì ń fi ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ohun tó ṣẹ́ kù mọ́lẹ̀;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́