-
Dáníẹ́lì 2:34, 35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ò ń wò títí a fi gé òkúta kan jáde, tó jẹ́ pé ọwọ́ kọ́ ló gé e, ó kọ lu ère náà ní àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀ tó jẹ́ irin àti amọ̀, ó sì fọ́ ọ túútúú.+ 35 Ìgbà yẹn ni gbogbo irin, amọ̀, bàbà, fàdákà àti wúrà fọ́ túútúú, ó sì dà bí ìyàngbò* láti ibi ìpakà ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn, atẹ́gùn sì gbé wọn lọ títí kò fi ṣẹ́ ku nǹkan kan. Àmọ́ òkúta tó kọ lu ère náà di òkè ńlá, ó sì bo gbogbo ayé.
-