ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 17:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Dáfídì wá fi kún un pé: “Jèhófà tó gbà mí lọ́wọ́* kìnnìún àti bíárì náà, ló máa gbà mí lọ́wọ́ Filísínì yìí.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ, kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”

  • Sáàmù 27:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi.

      Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+

      Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+

      Ta ni èmi yóò fòyà?

  • Àìsáyà 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+

      Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+

      Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,

      Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+

  • Dáníẹ́lì 6:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ó ń gbani sílẹ̀,+ ó ń gbani là, ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu ní ọ̀run àti ní ayé,+ torí ó gba Dáníẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn kìnnìún.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́