Sáàmù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà ni Ọba títí láé àti láéláé.+ Àwọn orílẹ̀-èdè ti ṣègbé kúrò láyé.+ Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+ Jeremáyà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.