-
Dáníẹ́lì 2:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Dáníẹ́lì wá lọ sí ilé rẹ̀, ó sì sọ ọ̀rọ̀ náà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀, Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà. 18 Ó ní kí wọ́n gbàdúrà sí Ọlọ́run ọ̀run fún àánú nípa àṣírí yìí, kí wọ́n má bàa pa Dáníẹ́lì àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ run pẹ̀lú àwọn amòye Bábílónì yòókù.
-