-
Jẹ́nẹ́sísì 41:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Torí náà, Fáráò sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ǹjẹ́ ọkùnrin míì wà tó ní ẹ̀mí Ọlọ́run bí ẹni yìí?”