Dáníẹ́lì 4:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Àmọ́ torí wọ́n sọ pé kí wọ́n fi kùkùté igi náà sílẹ̀ pẹ̀lú gbòǹgbò rẹ̀,*+ ìjọba rẹ máa pa dà di tìrẹ lẹ́yìn tí o bá mọ̀ pé ọ̀run ló ń ṣàkóso.
26 “‘Àmọ́ torí wọ́n sọ pé kí wọ́n fi kùkùté igi náà sílẹ̀ pẹ̀lú gbòǹgbò rẹ̀,*+ ìjọba rẹ máa pa dà di tìrẹ lẹ́yìn tí o bá mọ̀ pé ọ̀run ló ń ṣàkóso.