-
Àìsáyà 47:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ ti tán ọ lókun.
-
-
Dáníẹ́lì 2:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Dáníẹ́lì dá ọba lóhùn pé: “Ìkankan nínú àwọn amòye, àwọn pidánpidán, àwọn àlùfáà onídán àti àwọn awòràwọ̀ ò lè sọ àṣírí tí ọba ń béèrè fún un.+
-
-
Dáníẹ́lì 5:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Wọ́n mú àwọn amòye àti àwọn pidánpidán wá síwájú mi, kí wọ́n lè ka ọ̀rọ̀ yìí, kí wọ́n sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, àmọ́ wọn ò lè sọ ohun tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí.+
-