Sefanáyà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà jẹ́ olódodo ní àárín rẹ̀;+ kò ní ṣe àìtọ́. Àràárọ̀ ló ń jẹ́ ká mọ ìdájọ́ rẹ̀,+Kì í yẹ̀ bí ojúmọ́ kì í ti í yẹ̀. Ṣùgbọ́n àwọn aláìṣòdodo kò ní ìtìjú.+
5 Jèhófà jẹ́ olódodo ní àárín rẹ̀;+ kò ní ṣe àìtọ́. Àràárọ̀ ló ń jẹ́ ká mọ ìdájọ́ rẹ̀,+Kì í yẹ̀ bí ojúmọ́ kì í ti í yẹ̀. Ṣùgbọ́n àwọn aláìṣòdodo kò ní ìtìjú.+