Hósíà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+
5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+