-
Hósíà 7:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Wọ́n gbé! Torí wọ́n sá kúrò lọ́dọ̀ mi.
Ìparun á bá wọn, torí wọ́n ti ṣẹ̀ mí!
Mo ṣe tán láti rà wọ́n pa dà, àmọ́ wọ́n pa irọ́ mọ́ mi.+
-