Àìsáyà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí lẹ máa ṣe ní ọjọ́ ìjíhìn,*+Tí ìparun bá wá láti ọ̀nà jíjìn?+ Ta lẹ máa sá lọ bá pé kó ràn yín lọ́wọ́,+Ibo lẹ sì máa fi ọrọ̀* yín sí?
3 Kí lẹ máa ṣe ní ọjọ́ ìjíhìn,*+Tí ìparun bá wá láti ọ̀nà jíjìn?+ Ta lẹ máa sá lọ bá pé kó ràn yín lọ́wọ́,+Ibo lẹ sì máa fi ọrọ̀* yín sí?