Hósíà 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ilẹ̀ á sì dá ọkà àti wáìnì tuntun àti òróró lóhùn;Àwọn náà á sì dá Jésírẹ́lì*+ lóhùn.