2 Àwọn Ọba 17:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́, ọba Ásíríà rí i pé Hóṣéà ti ń lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, nítorí ó rán àwọn òjíṣẹ́ sí Sóò ọba Íjíbítì,+ kò sì mú ìṣákọ́lẹ̀* wá fún ọba Ásíríà bíi ti àwọn ọdún àtẹ̀yìnwá. Nítorí náà, ọba Ásíríà tì í mọ́ inú ẹ̀wọ̀n, ó sì fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè é.
4 Àmọ́, ọba Ásíríà rí i pé Hóṣéà ti ń lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, nítorí ó rán àwọn òjíṣẹ́ sí Sóò ọba Íjíbítì,+ kò sì mú ìṣákọ́lẹ̀* wá fún ọba Ásíríà bíi ti àwọn ọdún àtẹ̀yìnwá. Nítorí náà, ọba Ásíríà tì í mọ́ inú ẹ̀wọ̀n, ó sì fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè é.