-
Ìsíkíẹ́lì 23:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ó bá àwọn tó dáa jù lára àwọn ọmọkùnrin Ásíríà ṣèṣekúṣe, ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* tó jẹ́ ti àwọn tí ọkàn rẹ̀ ń fà sí sọ ara rẹ̀ di ẹlẹ́gbin.+ 8 Kò jáwọ́ nínú iṣẹ́ aṣẹ́wó tó ṣe ní Íjíbítì, torí wọ́n ti bá a sùn nígbà èwe rẹ̀, wọ́n fọwọ́ pa á láyà nígbà tí kò tíì mọ ọkùnrin, wọ́n sì tẹ́ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ wọn lọ́rùn lára rẹ̀.*+
-