Ẹ́kísódù 12:50, 51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè àti Áárónì. Wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́. 51 Ọjọ́ yìí gan-an ni Jèhófà mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn* kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Sáàmù 77:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 O darí àwọn èèyàn rẹ bí agbo ẹran,+Lábẹ́ àbójútó* Mósè àti Áárónì.+
50 Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè àti Áárónì. Wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́. 51 Ọjọ́ yìí gan-an ni Jèhófà mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn* kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.