Àìsáyà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọ̀sán, o rọra ṣe ọgbà yí oko rẹ ká,Ní àárọ̀, o mú kí irúgbìn rẹ rú jáde,Àmọ́ ìkórè ò ní sí ní ọjọ́ àìsàn àti ìrora tí kò ṣeé wò sàn.+
11 Ní ọ̀sán, o rọra ṣe ọgbà yí oko rẹ ká,Ní àárọ̀, o mú kí irúgbìn rẹ rú jáde,Àmọ́ ìkórè ò ní sí ní ọjọ́ àìsàn àti ìrora tí kò ṣeé wò sàn.+