ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,

      Ó sì máa yanjú ọ̀rọ̀* láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn.

      Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,

      Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+

      Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,

      Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+

  • Ìsíkíẹ́lì 39:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn tó ń gbé ní àwọn ìlú Ísírẹ́lì yóò jáde lọ, wọ́n á sì fi àwọn ohun ìjà dáná, àwọn asà* àti àwọn apata, àwọn ọrun àti àwọn ọfà, àwọn kóńdó* àti àwọn aṣóró. Wọn yóò sì fi wọ́n dáná+ fún ọdún méje.

  • Sekaráyà 9:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Èmi yóò mú kẹ̀kẹ́ ẹṣin tí wọ́n fi ń jagun kúrò ní Éfúrémù

      Àti ẹṣin kúrò ní Jerúsálẹ́mù.

      Ọfà tí wọ́n fi ń jagun kò ní sí mọ́.

      Òun yóò sì kéde àlàáfíà fún àwọn orílẹ̀-èdè;+

      Yóò jọba láti òkun dé òkun

      Àti láti Odò* dé àwọn ìkángun ayé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́