Àwọn Onídàájọ́ 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ ẹ fi mí sílẹ̀, ẹ sì ń sin àwọn ọlọ́run míì.+ Ìdí nìyẹn tí mi ò fi ní gbà yín sílẹ̀ mọ́.+ Jeremáyà 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ‘Lóòótọ́, gẹ́gẹ́ bí aya tó hùwà àìṣòótọ́, tó sì kúrò lọ́dọ̀ ọkọ* rẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì ṣe hùwà àìṣòótọ́ sí mi,’+ ni Jèhófà wí.”
20 ‘Lóòótọ́, gẹ́gẹ́ bí aya tó hùwà àìṣòótọ́, tó sì kúrò lọ́dọ̀ ọkọ* rẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì ṣe hùwà àìṣòótọ́ sí mi,’+ ni Jèhófà wí.”