Hósíà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ fun ìwo+ ní Gíbíà àti kàkàkí ní Rámà! + Ẹ kígbe ogun ní Bẹti-áfénì,+ a ó tẹ̀ lé ọ, ìwọ Bẹ́ńjámínì! Hósíà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ̀rù máa ba àwọn tó ń gbé ní Samáríà torí òrìṣà ọmọ màlúù tó wà ní Bẹti-áfénì.+ Àwọn èèyàn rẹ̀ máa ṣọ̀fọ̀ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà ọlọ́run àjèjì ibẹ̀, tó máa ń yọ̀ lórí rẹ̀ àti ògo rẹ̀, máa ṣọ̀fọ̀,Nítorí pé a ó mú un kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ìgbèkùn.
8 Ẹ fun ìwo+ ní Gíbíà àti kàkàkí ní Rámà! + Ẹ kígbe ogun ní Bẹti-áfénì,+ a ó tẹ̀ lé ọ, ìwọ Bẹ́ńjámínì!
5 Ẹ̀rù máa ba àwọn tó ń gbé ní Samáríà torí òrìṣà ọmọ màlúù tó wà ní Bẹti-áfénì.+ Àwọn èèyàn rẹ̀ máa ṣọ̀fọ̀ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà ọlọ́run àjèjì ibẹ̀, tó máa ń yọ̀ lórí rẹ̀ àti ògo rẹ̀, máa ṣọ̀fọ̀,Nítorí pé a ó mú un kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ìgbèkùn.