Diutarónómì 28:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 O máa gbin àjàrà, o sì máa roko rẹ̀, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu, o ò sì ní rí nǹkan kan+ kó jọ, torí kòkòrò mùkúlú ló máa jẹ ẹ́. 40 Igi ólífì máa wà ní gbogbo ilẹ̀ rẹ, àmọ́ o ò ní rí òróró fi para, torí pé àwọn ólífì rẹ máa rẹ̀ dà nù.
39 O máa gbin àjàrà, o sì máa roko rẹ̀, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu, o ò sì ní rí nǹkan kan+ kó jọ, torí kòkòrò mùkúlú ló máa jẹ ẹ́. 40 Igi ólífì máa wà ní gbogbo ilẹ̀ rẹ, àmọ́ o ò ní rí òróró fi para, torí pé àwọn ólífì rẹ máa rẹ̀ dà nù.