Ẹ́kísódù 30:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ wọn àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀.+ 20 Tí wọ́n bá ń lọ sínú àgọ́ ìpàdé tàbí tí wọ́n bá sún mọ́ pẹpẹ láti ṣiṣẹ́, láti fi iná sun ọrẹ kó sì rú èéfín sí Jèhófà, kí wọ́n lo omi náà kí wọ́n má bàa kú.
19 Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ wọn àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀.+ 20 Tí wọ́n bá ń lọ sínú àgọ́ ìpàdé tàbí tí wọ́n bá sún mọ́ pẹpẹ láti ṣiṣẹ́, láti fi iná sun ọrẹ kó sì rú èéfín sí Jèhófà, kí wọ́n lo omi náà kí wọ́n má bàa kú.