Míkà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa retí Jèhófà.+ Màá dúró* de Ọlọ́run ìgbàlà mi.+ Ọlọ́run mi yóò gbọ́ mi.+ Hábákúkù 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Síbẹ̀, ní tèmi, màá yọ̀ gidigidi nínú Jèhófà;Inú mi yóò dùn nínú Ọlọ́run ìgbàlà mi.+