Jóẹ́lì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí orílẹ̀-èdè kan ti gòkè wá sí ilẹ̀ mi, ó lágbára gan-an, kò sì lóǹkà.+ Eyín kìnnìún ni eyín rẹ̀,+ páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ náà sì jẹ́ ti kìnnìún.
6 Torí orílẹ̀-èdè kan ti gòkè wá sí ilẹ̀ mi, ó lágbára gan-an, kò sì lóǹkà.+ Eyín kìnnìún ni eyín rẹ̀,+ páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ náà sì jẹ́ ti kìnnìún.