Ìfihàn 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn eéṣú náà rí bí àwọn ẹṣin tó ṣe tán láti jagun;+ ohun tó dà bí adé tí wọ́n fi wúrà ṣe wà ní orí wọn, ojú wọn sì dà bíi ti èèyàn,
7 Àwọn eéṣú náà rí bí àwọn ẹṣin tó ṣe tán láti jagun;+ ohun tó dà bí adé tí wọ́n fi wúrà ṣe wà ní orí wọn, ojú wọn sì dà bíi ti èèyàn,