Ìfihàn 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 wọ́n sì ní ìgbàyà tó dà bí èyí tí wọ́n fi irin ṣe. Ìró ìyẹ́ wọn sì dà bí ìró àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin tó ń sáré lọ sójú ogun.+
9 wọ́n sì ní ìgbàyà tó dà bí èyí tí wọ́n fi irin ṣe. Ìró ìyẹ́ wọn sì dà bí ìró àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin tó ń sáré lọ sójú ogun.+