Àìsáyà 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Adé* ìgbéraga* àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù+ gbéÀti ìtànná ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,Tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá tó jẹ́ ti àwọn tí wáìnì ti kápá wọn! Émọ́sì 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n ń fi abọ́ mu wáìnì+Wọ́n sì ń fi òróró tó dára jù lọ para. Àmọ́ àjálù tó dé bá Jósẹ́fù kò dùn wọ́n.*+
28 Adé* ìgbéraga* àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù+ gbéÀti ìtànná ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,Tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá tó jẹ́ ti àwọn tí wáìnì ti kápá wọn!
6 Wọ́n ń fi abọ́ mu wáìnì+Wọ́n sì ń fi òróró tó dára jù lọ para. Àmọ́ àjálù tó dé bá Jósẹ́fù kò dùn wọ́n.*+