ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Bí o bá máa pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì,” ni Jèhófà wí,

      “Bí o bá máa pa dà sọ́dọ̀ mi

      Kí o mú òrìṣà ẹ̀gbin rẹ kúrò níwájú mi,

      Nígbà náà, ìwọ kò ní jẹ́ ìsáǹsá.+

  • Hósíà 12:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 “Torí náà, pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ,+

      Má ṣe jẹ́ kí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti ìdájọ́ òdodo bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́,+

      Sì máa ní ìrètí nínú Ọlọ́run rẹ nígbà gbogbo.

  • Hósíà 14:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì,+

      Torí àṣìṣe rẹ ti mú kí o kọsẹ̀.

       2 Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí,

      Ẹ sọ fún un pé, ‘Jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ kí o sì gba ohun rere tí a mú wá,

      A ó sì fi ètè wa rú ẹbọ ìyìn sí ọ+ bí ẹni fi akọ ọmọ màlúù rúbọ.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́