Diutarónómì 28:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 O máa gbin àjàrà, o sì máa roko rẹ̀, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu, o ò sì ní rí nǹkan kan+ kó jọ, torí kòkòrò mùkúlú ló máa jẹ ẹ́.
39 O máa gbin àjàrà, o sì máa roko rẹ̀, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu, o ò sì ní rí nǹkan kan+ kó jọ, torí kòkòrò mùkúlú ló máa jẹ ẹ́.