Àìsáyà 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+ Àìsáyà 44:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí màá da omi sórí ẹni* tí òùngbẹ ń gbẹ,+Màá sì mú kí odò ṣàn lórí ilẹ̀ gbígbẹ. Màá da ẹ̀mí mi sórí ọmọ* rẹ +Àti ìbùkún mi sórí àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ. Ìsíkíẹ́lì 39:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mi ò ní fi ojú mi pa mọ́ fún wọn mọ́,+ torí màá tú ẹ̀mí mi sórí ilé Ísírẹ́lì,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+
3 Torí màá da omi sórí ẹni* tí òùngbẹ ń gbẹ,+Màá sì mú kí odò ṣàn lórí ilẹ̀ gbígbẹ. Màá da ẹ̀mí mi sórí ọmọ* rẹ +Àti ìbùkún mi sórí àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ.
29 Mi ò ní fi ojú mi pa mọ́ fún wọn mọ́,+ torí màá tú ẹ̀mí mi sórí ilé Ísírẹ́lì,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”