-
Sáàmù 48:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 A ti wá fi ojú wa rí ohun tí a ti gbọ́
Ní ìlú Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ní ìlú Ọlọ́run wa.
Ọlọ́run yóò fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin títí láé.+ (Sélà)
-
-
Émọ́sì 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 ‘Màá gbìn wọ́n sórí ilẹ̀ wọn,
A kò sì ní fà wọ́n tu mọ́
Kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ wí.”
-