Léfítíkù 25:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+ Émọ́sì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Ísírẹ́lì+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Torí wọ́n ta olódodo nítorí fàdákàÀti tálákà nítorí iye owó bàtà ẹsẹ̀ méjì.+
39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Ísírẹ́lì+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Torí wọ́n ta olódodo nítorí fàdákàÀti tálákà nítorí iye owó bàtà ẹsẹ̀ méjì.+