Ìsíkíẹ́lì 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n á kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ rẹ, wọ́n á kó àwọn ọjà rẹ bí ẹrù ogun,+ wọ́n á ya àwọn ògiri rẹ lulẹ̀, wọ́n á wó àwọn ilé rẹ tó rẹwà; wọ́n á wá da àwọn òkúta rẹ, àwọn iṣẹ́ tí o fi igi ṣe àti iyẹ̀pẹ̀ rẹ sínú omi.’
12 Wọ́n á kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ rẹ, wọ́n á kó àwọn ọjà rẹ bí ẹrù ogun,+ wọ́n á ya àwọn ògiri rẹ lulẹ̀, wọ́n á wó àwọn ilé rẹ tó rẹwà; wọ́n á wá da àwọn òkúta rẹ, àwọn iṣẹ́ tí o fi igi ṣe àti iyẹ̀pẹ̀ rẹ sínú omi.’