Jóẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ Íjíbítì yóò di ahoro,+Édómù yóò sì di aginjù tó dá páropáro,+Torí bí wọ́n ṣe hùwà ipá sí àwọn ará Júdà,+Ilẹ̀ àwọn tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.+
19 Àmọ́ Íjíbítì yóò di ahoro,+Édómù yóò sì di aginjù tó dá páropáro,+Torí bí wọ́n ṣe hùwà ipá sí àwọn ará Júdà,+Ilẹ̀ àwọn tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.+