ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 24:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Lákòókò yẹn, àwọn ìránṣẹ́ Nebukadinésárì ọba Bábílónì wá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì dó ti ìlú náà.+

  • 2 Àwọn Ọba 24:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ọba Bábílónì tún kó gbogbo àwọn jagunjagun lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì, ẹgbẹ̀rún méje (7,000) ni wọ́n àti ẹgbẹ̀rún kan (1,000) àwọn oníṣẹ́ ọnà àti àwọn oníṣẹ́ irin,* alágbára ni gbogbo wọn, wọ́n sì ti kọ́ iṣẹ́ ogun.

  • Jeremáyà 52:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Àwọn èèyàn tí Nebukadinésárì* kó lọ sí ìgbèkùn nìyí: ní ọdún keje, ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé mẹ́tàlélógún (3,023) àwọn Júù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́