-
Sáàmù 42:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ibú omi ń pe ibú omi
Nígbà tí àwọn omi rẹ tó ń dà ṣọ̀ọ̀rọ̀ ń dún.
Gbogbo omi rẹ tó ń ru gùdù ti bò mí mọ́lẹ̀.+