2 Sámúẹ́lì 22:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì síwá-sẹ́yìn, ó sì ń mì jìgìjìgì;+Àwọn ìpìlẹ̀ ọ̀run mì tìtì+Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+ Sáàmù 68:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọlọ́run, nígbà tí o darí* àwọn èèyàn rẹ,+Nígbà tí o gba aṣálẹ̀ kọjá, (Sélà) 8 Ayé mì tìtì;+Ọ̀run rọ òjò* nítorí Ọlọ́run;Sínáì yìí mì tìtì nítorí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
8 Ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì síwá-sẹ́yìn, ó sì ń mì jìgìjìgì;+Àwọn ìpìlẹ̀ ọ̀run mì tìtì+Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+
7 Ọlọ́run, nígbà tí o darí* àwọn èèyàn rẹ,+Nígbà tí o gba aṣálẹ̀ kọjá, (Sélà) 8 Ayé mì tìtì;+Ọ̀run rọ òjò* nítorí Ọlọ́run;Sínáì yìí mì tìtì nítorí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+