Sáàmù 97:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mànàmáná rẹ̀ mú kí ilẹ̀ mọ́lẹ̀ kedere;Ayé rí i, ó sì ń gbọ̀n.+ 5 Àwọn òkè yọ́ bí ìda níwájú Jèhófà,+Níwájú Olúwa gbogbo ayé. Àìsáyà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wò ó! Jèhófà máa sọ ilẹ̀ náà* di òfìfo, ó sì máa sọ ọ́ di ahoro.+ Ó ń dojú rẹ̀ dé,*+ ó sì ń tú àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ ká.+
4 Mànàmáná rẹ̀ mú kí ilẹ̀ mọ́lẹ̀ kedere;Ayé rí i, ó sì ń gbọ̀n.+ 5 Àwọn òkè yọ́ bí ìda níwájú Jèhófà,+Níwájú Olúwa gbogbo ayé.
24 Wò ó! Jèhófà máa sọ ilẹ̀ náà* di òfìfo, ó sì máa sọ ọ́ di ahoro.+ Ó ń dojú rẹ̀ dé,*+ ó sì ń tú àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ ká.+