Sáàmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí Jèhófà mọ ọ̀nà àwọn olódodo,+Àmọ́ ọ̀nà àwọn èèyàn burúkú máa ṣègbé.+