Diutarónómì 32:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’ Diutarónómì 32:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Tí mo bá pọ́n idà mi tó ń kọ mànà,Tí mo sì múra ọwọ́ mi sílẹ̀ láti ṣèdájọ́,+Màá san àwọn ọ̀tá+ mi lẹ́san,Màá sì fìyà jẹ àwọn tó kórìíra mi. Àìsáyà 59:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.
35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’
41 Tí mo bá pọ́n idà mi tó ń kọ mànà,Tí mo sì múra ọwọ́ mi sílẹ̀ láti ṣèdájọ́,+Màá san àwọn ọ̀tá+ mi lẹ́san,Màá sì fìyà jẹ àwọn tó kórìíra mi.
18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.