-
Sefanáyà 2:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Èyí ni ìlú agbéraga tó wà ní ààbò,
Tó ń sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé, ‘Èmi ni, kò sì sí ẹlòmíì.’
Ẹ wo bó ṣe di ohun àríbẹ̀rù,
Ibi tí àwọn ẹranko ìgbẹ́ dùbúlẹ̀ sí!
Gbogbo ẹni tó bá ń gba ọ̀dọ̀ rẹ̀ kọjá á súfèé, á sì mi orí rẹ̀.”+
-