-
Sáàmù 104:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 O fi ibú omi bò ó bí aṣọ.+
Omi náà bo àwọn òkè.
7 Bí wọ́n ṣe gbọ́ ìbáwí rẹ, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ;+
Bí wọ́n ṣe gbọ́ ìró ààrá rẹ, ìbẹ̀rù mú kí wọ́n sá lọ
-
Sáàmù 107:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ó mú kí ìjì náà rọlẹ̀,
Ìgbì òkun sì pa rọ́rọ́.+
-
-
-