Àìsáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ni mo bá sọ pé: “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” Ó dáhùn pé: “Títí àwọn ìlú náà fi máa fọ́ túútúú, tí kò sì ní sẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀,Tí kò ní sẹ́nì kankan nínú àwọn ilé,Títí ilẹ̀ náà fi máa pa run, tó sì máa di ahoro;+
11 Ni mo bá sọ pé: “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” Ó dáhùn pé: “Títí àwọn ìlú náà fi máa fọ́ túútúú, tí kò sì ní sẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀,Tí kò ní sẹ́nì kankan nínú àwọn ilé,Títí ilẹ̀ náà fi máa pa run, tó sì máa di ahoro;+