Ìsíkíẹ́lì 14:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ọmọ èèyàn, àwọn ọkùnrin yìí ti pinnu láti máa tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* wọn, wọ́n sì ti ṣe ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí àwọn èèyàn dẹ́ṣẹ̀. Ṣé kí n jẹ́ kí wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi?+
3 “Ọmọ èèyàn, àwọn ọkùnrin yìí ti pinnu láti máa tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* wọn, wọ́n sì ti ṣe ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí àwọn èèyàn dẹ́ṣẹ̀. Ṣé kí n jẹ́ kí wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi?+