-
Ẹ́sírà 4:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ìgbà náà ni iṣẹ́ ilé Ọlọ́run, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù, dáwọ́ dúró; ó sì wà bẹ́ẹ̀ títí di ọdún kejì ìjọba Dáríúsì ọba Páṣíà.+
-
-
Hágáì 2:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kẹsàn-án, ọdún kejì ìjọba Dáríúsì, Jèhófà sọ fún wòlíì Hágáì+ pé:
-