Ẹ́sírà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà náà, wòlíì Hágáì+ àti wòlíì Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò+ sọ tẹ́lẹ̀ fún àwọn Júù tó wà ní Júdà àti ní Jerúsálẹ́mù, ní orúkọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń darí wọn.
5 Nígbà náà, wòlíì Hágáì+ àti wòlíì Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò+ sọ tẹ́lẹ̀ fún àwọn Júù tó wà ní Júdà àti ní Jerúsálẹ́mù, ní orúkọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń darí wọn.