Jóẹ́lì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà yóò ní ìtara nítorí ilẹ̀ rẹ̀,Yóò sì ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀.+ Sekaráyà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “‘Màá ní ìtara tó pọ̀ fún Síónì,+ tìbínútìbínú sì ni màá fi ní ìtara fún un,’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”
2 “‘Màá ní ìtara tó pọ̀ fún Síónì,+ tìbínútìbínú sì ni màá fi ní ìtara fún un,’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”