-
Ìsíkíẹ́lì 34:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “Màá wá èyí tó sọ nù,+ màá mú èyí tó rìn lọ pa dà wálé, màá fi aṣọ wé èyí tó fara pa, màá sì tọ́jú èyí tó rẹ̀ kó lè lágbára; àmọ́ èmi yóò pa èyí tó sanra àti èyí tó lágbára. Èmi yóò dá a lẹ́jọ́.”
17 “‘Ní tiyín, ẹ̀yin àgùntàn mi, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Mo máa tó ṣèdájọ́ láàárín àgùntàn kan àti àgùntàn mìíràn, láàárín àwọn àgbò àti àwọn òbúkọ.+
-